Isa 26:9
Isa 26:9 Yoruba Bible (YCE)
Ọkàn mi ń ṣe àfẹ́rí rẹ lálẹ́, mo sì ń fi tọkàntọkàn wá ọ nítorí nígbà tí ìlànà rẹ bá wà láyé ni àwọn ọmọ aráyé yóo kọ́ òdodo.
Pín
Kà Isa 26Isa 26:9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọkàn mi li emi fi ṣe afẹ̃ri rẹ li oru; nitõtọ, pẹlu ẹmi mi ninu mi li emi o wá ọ ni kutùkutù; nitori nigbati idajọ rẹ mbẹ ni ilẹ, awọn ti mbẹ li aiye yio kọ́ ododo.

Kà Isa 26Isa 26:9 Yoruba Bible (YCE)

Kà Isa 26