Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Isa 2:8YBCV(Bibeli Mimọ)

Ilẹ wọn kún fun oriṣa pẹlu; nwọn mbọ iṣẹ ọwọ́ ara wọn, eyiti ika awọn tikalawọn ti ṣe.

Isa 2:8BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ilẹ̀ ẹ wọn kún fún ère, wọ́n sì ń foríbalẹ̀ fún iṣẹ́ ọwọ́ ara wọn, èyí tí ìka ọwọ́ àwọn tìkára wọn ti ṣe.

Isa 2:8YCE(Yoruba Bible)

Ilẹ̀ wọn kún fún oriṣa, wọ́n ń bọ iṣẹ́ ọwọ́ ara wọn, wọ́n ń wólẹ̀ fún ohun tí wọ́n fọwọ́ ara wọn ṣe.