Nitorina inu mi yio dún bi harpu fun Moabu, ati ọkàn mi fun Kir-haresi.
Nítorí náà, ẹ̀mí mi kọrin arò bíi ti dùùrù fún Moabu, ọkàn mi kérora, fún Moabu ati Kiri Heresi.
Ọkàn mi kérora fún Moabu gẹ́gẹ́ bí i dùùrù, àní tọkàntọkàn mi fún ìlú Kiri-Hareseti.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò