Isa 1:1
Isa 1:1 Yoruba Bible (YCE)
Ìran tí Aisaya ọmọ Amosi rí sí Juda ati Jerusalẹmu nìyí, nígbà ayé Usaya, Jotamu, Ahasi, ati Hesekaya, àwọn ọba Juda.
Pín
Kà Isa 1Isa 1:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
IRAN Isaiah ọmọ Amosi, ti o rí nipa Juda ati Jerusalemu li ọjọ Ussiah, Jotamu, Ahasi, ati Hesekiah, awọn ọba Juda.
Pín
Kà Isa 1