Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Hos 7:3YBCV(Bibeli Mimọ)
Nwọn fi ìwa-buburu wọn mu ki ọba yọ̀; nwọn si fi eké wọn mu awọn ọmọ-alade yọ̀.
Hos 7:3BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Wọ́n ń mú inú ọba dùn pẹ̀lú ìwà búburú wọn, àti inú ọmọ-aládé dùn pẹ̀lú irọ́ wọn.
Hos 7:3YCE(Yoruba Bible)
OLUWA wí pé, “Àwọn eniyan ń dá ọba ninu dùn, nípa ìwà ibi wọn, wọ́n ń mú àwọn ìjòyè lóríyá nípa ìwà ẹ̀tàn wọn.