Hos 6:6
Hos 6:6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ãnu ni mo fẹ́, ki iṣe ẹbọ; ati ìmọ Ọlọrun jù ọrẹ-ẹbọ sisun lọ.
Pín
Kà Hos 6Hos 6:6 Yoruba Bible (YCE)
Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ ni mo fẹ́, kì í ṣe ẹbọ rírú; ìmọ̀ Ọlọrun ni mo bèèrè, kì í ṣe ẹbọ sísun.
Pín
Kà Hos 6