Hos 4:16 - Compare All Versions

Hos 4:16 YBCV (Bibeli Mimọ)

Nitori Israeli ṣe agidi bi ọmọ malu alagidi; nisisiyi Oluwa yio bọ́ wọn bi ọdọ-agùtan ni ibi ayè nla.

Hos 4:16 YCE (Yoruba Bible)

Israẹli ń ṣe agídí bí ọ̀dọ́ mààlúù tí ó ya olóríkunkun; ṣe OLUWA lè máa bọ́ wọn bí aguntan nisinsinyii lórí pápá tí ó tẹ́jú.

Hos 4:16 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Àwọn ọmọ Israẹli ṣe agídí bí alágídí ọmọ màlúù. Báwo wá ni OLúWA ṣe fẹ́ bọ́ wọn bí àgùntàn ní pápá oko tútù?