Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Hos 3:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni mo rà a fun ara mi ni fadakà mẹ̃dogun, ati homeri barli kan pẹlu ãbọ̀
Pín
Hos 3YBCVHos 3:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, mo sì rà á padà ní ṣékélì fàdákà mẹ́ẹ̀ẹ́dógún àti homeri kan àti lẹ́tékì barle kan.
Pín
Hos 3BMYOHos 3:2YCE(Yoruba Bible)
Nítorí náà, mo rà á ní ṣekeli fadaka mẹẹdogun ati ìwọ̀n ọkà baali kan.
Pín
Hos 3YCE