Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Hos 2:6YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitorina kiyesi i, emi o fi ẹgún sagbàra yi ọ̀na rẹ̀ ka, emi o si mọ odi, ti on kì yio fi ri ọ̀na rẹ̀ mọ.
Pín
Hos 2YBCVHos 2:6BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, èmi ó fi ẹ̀gún dì í lọ́nà, Èmi ó mọ odi yí i ká kí ó má ba à rọ́nà lọ.
Pín
Hos 2BMYOHos 2:6YCE(Yoruba Bible)
Nítorí náà, n óo fi ẹ̀gún ṣe ọgbà yí i ká; n óo mọ odi yí i ká, tí kò fi ní rí ọ̀nà jáde.
Pín
Hos 2YCE