Heb 6:17 - Compare All Versions
Heb 6:17 YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu eyiti bi Ọlọrun ti nfẹ gidigidi lati fi aileyipada ìmọ rẹ̀ han fun awọn ajogún ileri, o fi ibura sãrin wọn.
Pín
Heb 6 YBCVHeb 6:17 YCE (Yoruba Bible)
Ní ọ̀nà kan náà, nígbà tí Ọlọrun fẹ́ fihàn gbangba fún àwọn ajogún ìlérí wí pé èrò òun kò yipada, ó ṣe ìlérí, ó sì fi ìbúra tì í.
Pín
Heb 6 YCEHeb 6:17 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú èyí tí Ọlọ́run, ẹni tí ń fẹ́ gidigidi láti fi àìlèyípadà ète rẹ̀ hàn fún àwọn ajogún ìlérí náà, ó fi ìbúra sáàrín wọn.
Pín
Heb 6 BMYO