Heb 11:24
Heb 11:24 Yoruba Bible (YCE)
Nígbà tí Mose dàgbà tán, nípa igbagbọ ni ó fi kọ̀, tí kò jẹ́ kí wọ́n pe òun ní ọmọ ọmọbinrin Farao.
Pín
Kà Heb 11Heb 11:24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nipa igbagbọ́ ni Mose, nigbati o dàgba, o kọ̀ ki a mã pè on li ọmọ ọmọbinrin Farao
Pín
Kà Heb 11