Heb 11:1-2
Heb 11:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
NJẸ igbagbọ́ ni idaniloju ohun ti a nreti, ijẹri ohun ti a kò ri. Nitori ninu rẹ̀ li awọn alàgba ti ni ẹri rere.
Pín
Kà Heb 11Heb 11:1-2 Yoruba Bible (YCE)
Igbagbọ ni ìdánilójú ohun tí à ń retí, ẹ̀rí tí ó dájú nípa àwọn ohun tí a kò rí. Igbagbọ ni àwọn àgbà àtijọ́ ní, tí wọ́n fi ní ẹ̀rí rere.
Pín
Kà Heb 11