Hab 3:1-2
Hab 3:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
ADURA Habakuku woli lara Sigionoti. Oluwa, mo ti gbọ́ ohùn rẹ, ẹ̀ru si bà mi: Oluwa, mu iṣẹ rẹ sọji lãrin ọdun, lãrin ọdun sọ wọn di mimọ̀; ni ibinu ranti ãnu.
Pín
Kà Hab 3ADURA Habakuku woli lara Sigionoti. Oluwa, mo ti gbọ́ ohùn rẹ, ẹ̀ru si bà mi: Oluwa, mu iṣẹ rẹ sọji lãrin ọdun, lãrin ọdun sọ wọn di mimọ̀; ni ibinu ranti ãnu.