Gẹn 6:14 - Compare All Versions
Gẹn 6:14 YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ fi igi goferi kàn ọkọ́ kan; ikele-ikele ni iwọ o ṣe ninu ọkọ́ na, iwọ o si fi ọ̀da kùn u ninu ati lode.
Pín
Gẹn 6 YBCVGẹn 6:14 YCE (Yoruba Bible)
Nítorí náà, fi igi goferi kan ọkọ̀ ojú omi fún ara rẹ. Ṣe ọpọlọpọ yàrá sinu rẹ̀, kí o sì fi ọ̀dà kùn ún ninu ati lóde.
Pín
Gẹn 6 YCEGẹn 6:14 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà fi igi ọ̀mọ̀ kan ọkọ̀, kí o sì yọ yàrá sí inú rẹ̀, kí o sì fi ọ̀dà ilẹ̀ rẹ́ ẹ tinú-tẹ̀yìn.
Pín
Gẹn 6 BMYO