Gẹn 50:18 - Compare All Versions
Gẹn 50:18 YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn arakunrin rẹ̀ si lọ pẹlu, nwọn wolẹ niwaju rẹ̀: nwọn si wipe, Wò o, iranṣẹ rẹ li awa iṣe.
Pín
Gẹn 50 YBCVGẹn 50:18 YCE (Yoruba Bible)
Àwọn arakunrin rẹ̀ náà sì wá, wọ́n wólẹ̀ níwájú rẹ̀, wọ́n ní, “Wò ó, a di ẹrú rẹ.”
Pín
Gẹn 50 YCEGẹn 50:18 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn arákùnrin rẹ̀ wá, wọ́n sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀, wọ́n wí pé, “Ẹrú rẹ ni a jẹ́.”
Pín
Gẹn 50 BMYO