Gẹn 49:22-23
Gẹn 49:22-23 Yoruba Bible (YCE)
Josẹfu dàbí igi eléso tí ó wà lẹ́bàá odò, àwọn ẹ̀ka rẹ̀ nà mọ́ ara ògiri. Àwọn tafàtafà gbógun tì í kíkankíkan, wọ́n ń ta á lọ́fà, wọ́n sì ń dà á láàmú gidigidi
Pín
Kà Gẹn 49Gẹn 49:22-23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Josefu li ẹka eleso pupọ̀, ẹka eleso pupọ̀ li ẹba kanga; ẹtun ẹniti o yọ si ori ogiri. Awọn tafàtafa bà a ninu jẹ́ pọ̀ju, nwọn si tafà si i, nwọn si korira rẹ̀
Pín
Kà Gẹn 49Gẹn 49:22-23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“Josẹfu jẹ́ àjàrà eléso, àjàrà eléso ní etí odò, tí ẹ̀ka rẹ̀ gun orí odi. Pẹ̀lú ìkorò, àwọn tafàtafà dojú ìjà kọ ọ́, wọ́n tafà sí í pẹ̀lú ìkanra

Kà Gẹn 49