Gẹn 45:6
Gẹn 45:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ìyàn tí ó ti mú láti ọdún méjì sẹ́yìn yìí yóò tẹ̀síwájú fún ọdún márùn-ún sí i nínú èyí tí ẹnikẹ́ni kò ní gbìn, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ni kórè.
Pín
Kà Gẹn 45Gẹn 45:6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Lati ọdún meji yi ni ìyan ti nmú ni ilẹ: o si tun kù ọdún marun si i, ninu eyiti a ki yio ni itulẹ tabi ikorè.
Pín
Kà Gẹn 45