Gẹn 41:51
Gẹn 41:51 Yoruba Bible (YCE)
Josẹfu sọ ọmọ rẹ̀ kinni ní Manase, ó ní, “Ọlọ́run ti mú mi gbàgbé gbogbo ìnira mi ati ilé baba mi.”
Pín
Kà Gẹn 41Gẹn 41:51 Bibeli Mimọ (YBCV)
Josefu si sọ orukọ akọ́bi ni Manasse: wipe, Nitori ti Ọlọrun mu mi gbagbe gbogbo iṣẹ́ mi, ati gbogbo ile baba mi.
Pín
Kà Gẹn 41