Gẹn 37:31 - Compare All Versions
Gẹn 37:31 YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si mú ẹ̀wu Josefu, nwọn si pa ọmọ ewurẹ kan, nwọn si rì ẹ̀wu na sinu ẹ̀jẹ na.
Pín
Gẹn 37 YBCVGẹn 37:31 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni wọ́n mú aṣọ Josẹfu, wọ́n pa ewúrẹ́ kan, wọ́n sì tẹ aṣọ náà bọ inú ẹ̀jẹ̀ ewúrẹ́ náà.
Pín
Gẹn 37 BMYOGẹn 37:31 YCE (Yoruba Bible)
Wọ́n bá mú ọmọ ewúrẹ́ kan ninu agbo, wọ́n pa á, wọ́n sì ti ẹ̀wù Josẹfu bọ inú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.
Pín
Gẹn 37 YCE