Gẹn 28:22
Gẹn 28:22 Yoruba Bible (YCE)
Òkúta tí mo sì gbé nàró bí ọ̀wọ̀n yìí yóo di ilé Ọlọrun, n óo sì fún ìwọ Ọlọrun ní ìdámẹ́wàá ohun gbogbo tí o bá fún mi.”
Pín
Kà Gẹn 28Gẹn 28:22 Bibeli Mimọ (YBCV)
Okuta yi, ti mo fi lelẹ ṣe ọwọ̀n ni yio si ṣe ile Ọlọrun: ati ninu ohun gbogbo ti iwọ o fi fun mi, emi o si fi idamẹwa rẹ̀ fun ọ.
Pín
Kà Gẹn 28