Gẹn 25:30 - Compare All Versions
Gẹn 25:30 YBCV (Bibeli Mimọ)
Esau si wi fun Jakobu pe, Emi bẹ̀ ọ, fi ìpẹtẹ rẹ pupa nì bọ́ mi; nitori ti o rẹ̀ mi: nitori na li a ṣe npè orukọ rẹ̀ ni Edomu.
Pín
Gẹn 25 YBCVGẹn 25:30 YCE (Yoruba Bible)
Esau sọ fún Jakọbu pé, “Jọ̀wọ́ fún mi jẹ ninu ẹ̀bẹ tí ó pupa yìí nítorí pé ebi ń pa mí kú lọ.” (Nítorí ọ̀rọ̀ yìí ni wọ́n ṣe ń pè é ní Edomu.)
Pín
Gẹn 25 YCEGẹn 25:30 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Esau wí fún Jakọbu pé, “Èmí bẹ̀ ọ, fi ìpẹ̀tẹ̀ rẹ pupa n nì bọ́ mi, nítorí tí ó rẹ̀ mí gidigidi.” (Nítorí náà ni a ṣe ń pe orúkọ rẹ̀ ní Edomu.)
Pín
Gẹn 25 BMYO