Gẹn 22:14 - Compare All Versions
Gẹn 22:14 YBCV (Bibeli Mimọ)
Abrahamu si pè orukọ ibẹ̀ na ni Jehofajire: bi a ti nwi titi di oni yi, Li oke OLUWA li a o gbé ri i.
Pín
Gẹn 22 YBCVGẹn 22:14 YCE (Yoruba Bible)
Nítorí náà ni Abrahamu ṣe sọ ibẹ̀ ní “OLUWA yóo pèsè,” bí wọ́n ti ń wí títí di òní, pé, “Ní orí òkè OLUWA ni yóo ti pèsè.”
Pín
Gẹn 22 YCEGẹn 22:14 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Abrahamu sì pe orúkọ ibẹ̀ ni, Jehofah Jire. Bẹ́ẹ̀ ni a sì ń wí títí di òní olónìí pé, “Ní orí òkè OLúWA, ni a ó ti pèsè.”
Pín
Gẹn 22 BMYO