Gẹn 2:15
Gẹn 2:15 Yoruba Bible (YCE)
OLUWA Ọlọrun fi ọkunrin tí ó dá sinu ọgbà Edẹni, kí ó máa ro ó, kí ó sì máa tọ́jú rẹ̀.
Pín
Kà Gẹn 2Gẹn 2:15 Bibeli Mimọ (YBCV)
OLUWA Ọlọrun si mu ọkunrin na, o si fi i sinu ọgbà Edeni lati ma ro o, ati lati ma ṣọ́ ọ.
Pín
Kà Gẹn 2