Gẹn 2:1-2
Gẹn 2:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
BẸ li a pari ọrun on aiye, ati gbogbo ogun wọn. Ni ijọ́ keje Ọlọrun si pari iṣẹ rẹ̀ ti o ti nṣe; o si simi ni ijọ́ keje kuro ninu iṣẹ rẹ̀ gbogbo ti o ti nṣe.
Pín
Kà Gẹn 2BẸ li a pari ọrun on aiye, ati gbogbo ogun wọn. Ni ijọ́ keje Ọlọrun si pari iṣẹ rẹ̀ ti o ti nṣe; o si simi ni ijọ́ keje kuro ninu iṣẹ rẹ̀ gbogbo ti o ti nṣe.