Gẹn 18:14
Gẹn 18:14 Yoruba Bible (YCE)
Ṣé ohun kan wà tí ó ṣòro fún OLUWA ni? Nígbà tí àkókò bá tó, n óo pada wá sọ́dọ̀ rẹ níwòyí ọdún tí ń bọ̀, Sara yóo bí ọmọkunrin kan.”
Pín
Kà Gẹn 18Gẹn 18:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ohun kan ha ṣoro fun OLUWA? li akoko ti a dá emi o pada tọ̀ ọ wa, ni iwoyi amọ́dun, Sara yio si li ọmọkunrin kan.
Pín
Kà Gẹn 18