Gẹn 13:8
Gẹn 13:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Abramu sì wí fún Lọti pé, “Èmi bẹ̀ ọ́, má ṣe jẹ́ kí èdè-àìyedè kí ó wà láàrín èmi àti ìrẹ, àti láàrín àwọn darandaran wa, nítorí pé ẹbí kan ni àwa ṣe.
Pín
Kà Gẹn 13Gẹn 13:8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Abramu si wi fun Loti pe, Emi bẹ̀ ọ, máṣe jẹ ki gbolohùn asọ̀ ki o wà lãrin temi tirẹ, ati lãrin awọn darandaran mi, ati awọn darandaran rẹ; nitori pe ará li awa iṣe.
Pín
Kà Gẹn 13