Gẹn 1:27
Gẹn 1:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Nítorí náà, Ọlọ́run dá ènìyàn ní àwòrán ara rẹ̀, ní àwòrán Ọlọ́run ni Ó dá a, akọ àti abo ni Ó dá wọn.
Pín
Kà Gẹn 1Gẹn 1:27 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bẹ̃li Ọlọrun dá enia li aworan rẹ̀, li aworan Ọlọrun li o dá a; ati akọ ati abo li o dá wọn.
Pín
Kà Gẹn 1Gẹn 1:27 Yoruba Bible (YCE)
Bẹ́ẹ̀ ni Ọlọrun dá eniyan ní àwòrán ara rẹ̀. Takọ-tabo ni ó dá wọn.
Pín
Kà Gẹn 1