Gal 4:4
Gal 4:4 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn nígbà tí ó tó àkókò tí ó wọ̀, Ọlọrun rán Ọmọ rẹ̀ wá. Obinrin ni ó bí i, ó bí i lábẹ́ òfin àwọn Juu
Pín
Kà Gal 4Gal 4:4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn nigbati akokò kíkun na de, Ọlọrun rán Ọmọ rẹ̀ jade wá, ẹniti a bí ninu obinrin, ti a bi labẹ ofin
Pín
Kà Gal 4