Gal 3:14
Gal 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ó gbà wá là ki ìbùkún Abrahamu ba à lè wá sórí àwọn aláìkọlà nípa Kristi Jesu; kí àwa ba à lè gba ìlérí Ẹ̀mí nípa ìgbàgbọ́.
Pín
Kà Gal 3Gal 3:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ki ibukún Abrahamu ki o le wá sori awọn Keferi nipa Kristi Jesu; ki awa ki o le gbà ileri Ẹmí nipa igbagbọ́.
Pín
Kà Gal 3