Gal 1:4-5
Gal 1:4-5 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹniti o fi on tikalarẹ̀ fun ẹ̀ṣẹ wa, ki o le gbà wa kuro ninu aiye buburu isisiyi, gẹgẹ bi ifẹ Ọlọrun ati Baba wa: Ẹniti ogo wà fun lai ati lailai. Amin.
Pín
Kà Gal 1Ẹniti o fi on tikalarẹ̀ fun ẹ̀ṣẹ wa, ki o le gbà wa kuro ninu aiye buburu isisiyi, gẹgẹ bi ifẹ Ọlọrun ati Baba wa: Ẹniti ogo wà fun lai ati lailai. Amin.