Gal 1:14
Gal 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Mo sì ta ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹlẹgbẹ́ mi yọ nínú ìsìn àwọn Júù láàrín àwọn ìran mi, mo sì ni ìtara lọ́pọ̀lọpọ̀ sì òfin àtọwọ́dọ́wọ́ àwọn baba mi.
Pín
Kà Gal 1Gal 1:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Mo si ta ọpọlọpọ awọn ẹlẹgbẹ́ mi yọ ninu isin awọn Ju larin awọn ara ilu mi, mo si ni itara lọpọlọpọ si ofin atọwọdọwọ awọn baba mi.
Pín
Kà Gal 1