Esek 8:3
Esek 8:3 Bibeli Mimọ (YBCV)
O si nà àworan ọwọ́ jade, o si mu mi ni ìdi-irun ori mi; ẹmi si gbe mi soke lagbedemeji aiye on ọrun, o si mu mi wá ni iran Ọlọrun si Jerusalemu, si ilẹkun ẹnu-ọ̀na ti inu to kọju si ariwa; nibiti ijoko ere owu wà ti nmu ni jowu.
Pín
Kà Esek 8Esek 8:3 Yoruba Bible (YCE)
Ó na nǹkankan tí ó dàbí ọwọ́, ó fi gbá ìdí irun orí mi mú, ẹ̀mí sì gbé mi sókè sí agbede meji ọ̀run ati ayé, ó gbé mi lọ sí Jerusalẹmu, ninu ìran Ọlọrun, ó gbé mi sí ẹnu ọ̀nà àgbàlá gbọ̀ngàn ti inú tí ó kọjú sí ìhà àríwá, níbi tí wọ́n gbé ère tí ń múni jowú sí.
Pín
Kà Esek 8