Esek 5:9
Esek 5:9 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí gbogbo ìwà ìríra yín, n óo ṣe ohun tí n kò ṣe rí si yín, tí n kò sì ní ṣe irú rẹ̀ mọ́ lae.
Pín
Kà Esek 5Esek 5:9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi o si ṣe ninu rẹ ohun ti emi kò ṣe ri, iru eyi ti emi kì yio si ṣe mọ, nitori gbogbo ohun irira rẹ.
Pín
Kà Esek 5