Esek 5:1
Esek 5:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
IWỌ, ọmọ enia, mu ọbẹ mimú, mu abẹ onigbajamọ̀, ki o si mu u kọja li ori rẹ, ati ni irùngbọn rẹ: si mu oṣuwọ̀n lati wọ̀n, ki o si pin irun na.
Pín
Kà Esek 5IWỌ, ọmọ enia, mu ọbẹ mimú, mu abẹ onigbajamọ̀, ki o si mu u kọja li ori rẹ, ati ni irùngbọn rẹ: si mu oṣuwọ̀n lati wọ̀n, ki o si pin irun na.