Eks 7:17
Eks 7:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Èyí ni OLúWA wí: Nípa èyí ni ìwọ yóò mọ̀ pé èmi ni OLúWA. Wò ó, èmi yóò fi ọ̀pá ti ó wà ní ọwọ́ mi, èmi yóò ná omi tí ó wà nínú odò Naili yóò sì di ẹ̀jẹ̀.
Pín
Kà Eks 7Eks 7:17 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bayi li OLUWA wi, Ninu eyi ni iwọ o fi mọ̀ pe emi li OLUWA: kiyesi i, emi o fi ọpá ti o wà li ọwọ́ mi lù omi ti o wà li odò, nwọn o si di ẹ̀jẹ.
Pín
Kà Eks 7