Eks 6:2-3
Eks 6:2-3 Yoruba Bible (YCE)
Ọlọrun tún sọ fún Mose pé, “Èmi ni OLUWA. Mo fara han Abrahamu, Isaaki, ati Jakọbu gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun Olodumare, ṣugbọn n kò farahàn wọ́n gẹ́gẹ́ bí OLUWA tíí ṣe orúkọ mi gan-an.
Pín
Kà Eks 6Eks 6:2-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọlọrun si sọ fun Mose, o si wi fun u pe, Emi ni JEHOFA: Emi si farahàn Abrahamu, Isaaki, ati Jakobu, li orukọ Ọlọrun Olodumare, ṣugbọn orukọ mi JEHOFA, ni nwọn kò fi mọ̀ mi.
Pín
Kà Eks 6