Eks 36:10 - Compare All Versions
Eks 36:10 YBCV (Bibeli Mimọ)
O si so aṣọ-tita marun lù mọ́ ara wọn: ati aṣọ-tita marun keji li o si solù mọ́ ara wọn.
Pín
Eks 36 YBCVEks 36:10 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Aṣọ títa márùn-ún ni kí a so papọ̀ mọ́ ara wọn, àti aṣọ títa márùn-ún ni kí a so papọ̀ mọ́ ara wọn.
Pín
Eks 36 BMYOEks 36:10 YCE (Yoruba Bible)
Ó rán marun-un ninu àwọn aṣọ títa náà pọ̀, ó sì rán marun-un yòókù pọ̀ lọ́tọ̀ọ̀tọ̀.
Pín
Eks 36 YCE