Eks 34:22
Eks 34:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“Ṣe àjọ ọ̀sẹ̀ pẹ̀lú àkọ́so èso alikama àti àjọ ìkórè ní òpin ọdún.
Pín
Kà Eks 34Eks 34:22 Bibeli Mimọ (YBCV)
Iwọ o si ma kiyesi ajọ ọ̀sẹ, akọ́so eso alikama, ati ajọ ikore li opin ọdún.
Pín
Kà Eks 34