Eks 27:10 - Compare All Versions
Eks 27:10 YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ogún opó rẹ̀, ati ogún ihò-ìtẹbọ wọn, ki o jẹ́ idẹ; ikọ́ opó wọnni ati ọpá isopọ̀ wọn ki o jẹ́ fadakà.
Pín
Eks 27 YBCVEks 27:10 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
pẹ̀lú ogún òpó àti ogún ihò ìtẹ̀bọ̀ idẹ pẹ̀lú ìkọ́ fàdákà, kí ó sì di àwọn òpó mú.
Pín
Eks 27 BMYOEks 27:10 YCE (Yoruba Bible)
àwọn òpó rẹ̀ yóo jẹ́ ogún, ìtẹ́lẹ̀ rẹ̀ yóo sì jẹ́ ogún bákan náà, idẹ ni o óo fi ṣe wọ́n, ṣugbọn fadaka ni kí o fi ṣe àwọn ìkọ́ ati òpó rẹ̀.
Pín
Eks 27 YCE