Eks 26:3 - Compare All Versions

Eks 26:3 YBCV (Bibeli Mimọ)

Aṣọ-tita marun ni ki a solù mọ́ ara wọn; ati aṣọ-tita marun keji ni ki a solù mọ́ ara wọn.

Eks 26:3 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Aṣọ títa márùn-ún ni kí a so papọ̀ mọ́ ara wọn, àti aṣọ títa márùn-ún ni kí a so papọ̀ mọ́ ara wọn.

Eks 26:3 YCE (Yoruba Bible)

Rán marun-un ninu àwọn aṣọ títa náà pọ̀, lẹ́yìn náà, rán marun-un yòókù pọ̀.