Eks 20:6 - Compare All Versions
Eks 20:6 YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi a si ma fi ãnu hàn ẹgbẹgbẹrun awọn ti o fẹ́ mi, ti nwọn si npa ofin mi mọ́.
Pín
Eks 20 YBCVEks 20:6 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi a sì máa fi àánú hàn sí ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn tí ó fẹ́ mi, tí wọ́n sì ń pa òfin mi mọ́.
Pín
Eks 20 BMYOEks 20:6 YCE (Yoruba Bible)
Ṣugbọn èmi a máa fi ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ hàn sí ẹgbẹẹgbẹrun àwọn tí wọ́n fẹ́ mi, tí wọ́n sì ń pa òfin mi mọ́.
Pín
Eks 20 YCE