Eks 12:51 - Compare All Versions

Eks 12:51 YBCV (Bibeli Mimọ)

O si ṣe li ọjọ́ na gan, OLUWA mú awọn ọmọ Israeli jade kuro ni ilẹ Egipti, gẹgẹ bi ogun wọn.

Eks 12:51 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Àti pé ní ọjọ́ náà gan an ni OLúWA mú àwọn ọmọ Israẹli jáde kúrò ní ilẹ̀ Ejibiti gẹ́gẹ́ bí ìpín ìpín wọn.

Eks 12:51 YCE (Yoruba Bible)

Ní ọjọ́ yìí gan-an ni OLUWA mú àwọn ẹ̀yà Israẹli jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti.