Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Est 9:4YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori Mordekai tobi ni ile ọba, okiki rẹ̀ si kàn ja gbogbo ìgberiko: nitori ọkunrin yi Mordekai ntobi siwaju ati siwaju.
Est 9:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mordekai sì jẹ́ ẹni pàtàkì ní ààfin ọba, òkìkí rẹ̀ sì tàn jákèjádò àwọn ìgbèríko, ó sì ní agbára kún agbára.
Est 9:4YCE(Yoruba Bible)
Modekai di eniyan pataki ní ààfin; òkìkí rẹ̀ kàn dé gbogbo agbègbè, agbára rẹ̀ sì ń pọ̀ sí i.