Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Est 8:4YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbana ni ọba nà ọpá-alade wura si Esteri. Bẹ̃ni Esteri dide, o si duro niwaju ọba.
Pín
Est 8YBCVEst 8:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ọba na ọ̀pá aládé wúrà sí Esteri ó sì dìde, ó dúró níwájú rẹ̀.
Pín
Est 8BMYO