Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Est 7:5YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Ahaswerusi ọba dahùn, o si wi fun Esteri ayaba pe, Tali oluwa rẹ̀ na, nibo li o si wà, ti o jẹ gbe e le ọkàn rẹ̀ lati ṣe bẹ̃?
Pín
Est 7YBCVEst 7:5BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba Ahaswerusi bi Esteri ayaba léèrè pé, “Ta a ni ẹni náà? Níbo ni ẹni náà wà tí kò bẹ̀rù láti ṣe irú nǹkan bẹ́ẹ̀?”
Pín
Est 7BMYOEst 7:5YCE(Yoruba Bible)
Ahasu-erusi ọba bi Ẹsita Ayaba pé, “Ta ni olúwarẹ̀, níbo ni ẹni náà wà, tí ń gbèrò láti dán irú nǹkan bẹ́ẹ̀ wò?”
Pín
Est 7YCE