Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Est 6:7YBCV(Bibeli Mimọ)
Hamani si da ọba lohùn pe, ọkunrin na ẹniti inu ọba dùn si lati bù ọlá fun.
Pín
Est 6YBCVEst 6:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà Hamani dá ọba lóhùn pé, “Fún ọkùnrin tí inú ọba dùn sí láti dá lọ́lá
Pín
Est 6BMYOEst 6:7YCE(Yoruba Bible)
Nítorí náà, ó dá ọba lóhùn pé, “Báyìí ni ó ṣe yẹ kí á dá ẹni tí inú ọba dùn sí lọ́lá
Pín
Est 6YCE