Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Est 3:5YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbati Hamani si ri pe, Mordekai kò kunlẹ, bẹ̃ni kò wolẹ fun on, nigbana ni Hamani kún fun ibinu.
Pín
Est 3YBCVEst 3:5BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Hamani rí i pé Mordekai kò ní kúnlẹ̀ tàbí bu ọlá fún òun, ó bínú.
Pín
Est 3BMYOEst 3:5YCE(Yoruba Bible)
Nígbà tí Hamani rí i pé Modekai kọ̀, kò foríbalẹ̀ fún òun, inú bí i pupọ.
Pín
Est 3YCE