Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Est 3:14YBCV(Bibeli Mimọ)
Ọ̀ran iwe na ni lati paṣẹ ni gbogbo igberiko, lati kede rẹ̀ fun gbogbo enia, ki nwọn ki o le mura de ọjọ na.
Pín
Est 3YBCVEst 3:14BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ẹ mú àdàkọ ìwé náà kí a tẹ̀ ẹ́ jáde bí òfin ní gbogbo ìgbèríko kí ó sì di mí mọ̀ fún àwọn ènìyàn ìlú nítorí kí wọ́n le múra fún ọjọ́ náà.
Pín
Est 3BMYOEst 3:14YCE(Yoruba Bible)
Wọ́n níláti sọ ohun tí ó wà ninu ìwé náà di òfin ní gbogbo ìgbèríko, kí wọ́n sì sọ fún gbogbo eniyan, kí wọ́n lè múra sílẹ̀ de ọjọ́ náà.
Pín
Est 3YCE