Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Est 2:6YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹniti a ti mu lọ lati Jerusalemu pẹlu ìgbekun ti a kó lọ pẹlu Jekoniah, ọba Juda, ti Nebukadnessari, ọba Babeli ti kó lọ.
Pín
Est 2YBCVEst 2:6BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ẹni tí Nebukadnessari ọba Babeli ti gbé lọ sí ìgbèkùn láti Jerusalẹmu, lára àwọn tí wọ́n kó ní ìgbèkùn pẹ̀lú ọba Jekoniah ọba Juda.
Pín
Est 2BMYOEst 2:6YCE(Yoruba Bible)
Ó wà lára àwọn tí Nebukadinesari ọba Babiloni kó lẹ́rú láti Jerusalẹmu lọ sí ilẹ̀ Babiloni pẹlu Jekonaya, ọba Juda.
Pín
Est 2YCE