Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Est 2:16YBCV(Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li a mu Esteri wá si ọdọ Ahaswerusi ọba, sinu ile ọba, li oṣù kẹwa, ti iṣe oṣù Tibeti, li ọdun keje ijọba rẹ̀.
Pín
Est 2YBCVEst 2:16BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A mú Esteri lọ síwájú ọba Ahaswerusi ní ibùgbé ọba ní oṣù kẹwàá, tí ó jẹ́ oṣù Tebeti, ní ọdún keje ìjọba rẹ̀.
Pín
Est 2BMYOEst 2:16YCE(Yoruba Bible)
Wọ́n mú Ẹsita lọ sọ́dọ̀ ọba Ahasu-erusi ní ààfin rẹ̀ ní oṣù Tebeti, tíí ṣe oṣù kẹwaa, ní ọdún keje ìjọba rẹ̀.
Pín
Est 2YCE